🇳🇬 NIGERIA GOSPEL
Tope Alabi – Halleluyah
Follow Us On
WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
---|


Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – Halleluyah.
Award Winning Nigerian Christian Gospel female music minister, music singer, songwriter and worship leader, Tope Alabi has come through with another powerful brand new gospel music which she titled “Halleluyah”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!
Check Out The Full Lyrics Below;
Hallelujah ni won ma ko
Hallelujah si wo olurun mi Orin hallelujah ni woo bawon torun ko oOju orun fun dede
Awo San man ni Pele ni pele Eru lo fi ko aye Okun fun ajara Eda o yanbo Awo Ewo lo da Ara oto to MO korin hallelujah si wo tan awon Orun bo oMimo Mimo ni won ke
Awon ti Eda orun angeli lowo lowoo Won fi ojo jo fi ori bale o Agba gba n ke Mimo Si oludande aye gbogbo Hallelujah si oni ite ogo aditu Gbogboro owo to na aye ja lati inu orun wa Kikorin won o dake ri Si olurun awon omo ogunHallelujah ni won ko
Won segun aye ko si daru dapo Owun gbo lo Leto leto Ebi ko pa won ri beeni Ara ko ni won ri Kida ayo ekunrere alafia Awa ti a le ke hallelujah ninu aye Awa lafi Orin isegun se wa logo A o Jeri Ota a di Eni ite mole pata Orin hallelujah ni a fi ba Jesu joba Awa ti a gbalaDOWNLOAD AUDIO/MP3
Download Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments