🇳🇬 NIGERIA GOSPEL
Nigbati Mo Ro by Tope Alabi
Follow Us On
WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
---|


Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – Nigbati Mo Ro.
Award Winning Nigerian Christian Gospel female music minister, music singer, songwriter and worship leader, Tope Alabi has released another powerful brand new gospel music which she titled “Nigbati Mo Ro”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!
Check Out The Full Lyrics Below;
Lati inu oyun
Titi di omo owo o Igba mo wa lomo owo Awon ota gba wipe iku o pa miMo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye rara
Baba o sho mi, ore re yi o lakaweLati irakoro titi di omo irinse o sho mi
Titi mo fi wa di agbalagba oIgba ti mo ro, Ise Iyanu re laye mi
Mo wa ri pe o oga o pupoIgba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mo ri pe o ga Mo ri pe o ga Baba.Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, more ri pe o ga Mo ri pe o ga Baba.Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.Ogun ti eniyan ja n’agba, o poju Ogun ewe lo
Tori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju ko Idi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi mo ooo Oju ogun laye je feni to waye o wa se rere Mo wa ronu jinle Aanu re lori aye mi Emi ri pe o ga o, pupoIgba ti mi ro anu re lo ri mi
Mori pe oga, mo ri pe o ga Mo ri pe o ga Baba.Igba ti mo ro anu re lo ri mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mo ri pe o ga Mo ri pe o ga Baba.Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.Ose Olorun, Iwo lo je ki ewu aye fo mi da
Iya to je mi, o je ko je mi gbe o, baba o seun. A pe omo lowo eyin Oluso agun fun mi Olorun iwo ni Iwo lo gbe mi ro, eniyan o le seyi o afi iwo O gbe mi so ke gogoro, Osuba re o baba Eyi ni mo se isiro fun titi, ogbon ori mi ko gbeIgba ti mi ro ife nla re Lori mi
Mori pe oga, more ri pe o ga Mo ri pe o ga Baba.Igba ti mo ro ife nla re lori mi
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, more ri pe o ga Baba.Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,
Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.Olorun to ga owa loke
Olorun to be ninu aye Okere titi, ogba mimo eniyan Owa lotun wa, owa lo si wa Ayika wa gbogbo, owa ni be Ohun ni olorun, afeti lu Kara Larin alawo dudu o n sise e lo Eyin re eniyan, mo rin ise re Alawo funfun won teriba fun Alayi mo n kon, won beere wipe Tani olorun, ta lolorun Ayanfe ema da won lo wun pe Ibi gbogbo lo wa eh Olorun agbaye Ibi gbogbo lo wa eh Ani ko si ibiti oju olorun ko to Ibi gbogbo lo wa Olorun nla apejuba, arayerorun Ibi gbogbo lo wa Ibi gbogbo lolorun gbe Ibi gbogbo lo wa O nbe laye, emi awon woli to to Ibi gbogbo lo wa Oro gbe inu omo eniyan fo mu Ibi gbogbo lo wa Oti saju aye de, omo inu aye ati eyin aye Ibi gbogbo lo wa Ibi gbogbo lo wa olodumare Ibi gbogbo lo wa O nbe larin awon angeli mimo Ibi gbogbo lo wa Ko si ibiti e pe olorun si ti o wa oh Ibi gbogbo lo wa Ibi gbogbo lo wa baba oh Ibi gbogbo lo wa Olorun ajanaku, ibi gbogbo lo wa baba Ibi gbogbo lo wa O nbe lokan re ti o ba gba laye Ibi gbogbo lo wa Ibi gbogbo, ibi gbogbo lo wa Ibi gbogbo lo waDOWNLOAD AUDIO/MP3
Download Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments