🇳🇬 NIGERIA GOSPEL

Nigbati Mo Ro by Tope Alabi

Follow Us On
WHATSAPP GROUPTELEGRAM CHANNEL
Tope Alabi – Nigbati Mo Ro
Tope Alabi – Nigbati Mo Ro

Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – Nigbati Mo Ro.

Award Winning Nigerian Christian Gospel female music minister, music singer, songwriter and worship leader, Tope Alabi has released another powerful brand new gospel music which she titled “Nigbati Mo Ro”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!

 Check Out The Full Lyrics Below;

Lati inu oyunTiti di omo owo oIgba mo wa lomo owoAwon ota gba wipe iku o pa mi
Mo ra ko ro de ile olodia awon ti o fe n waye raraBaba o sho mi, ore re yi o lakawe
Lati irakoro titi di omo irinse o sho miTiti mo fi wa di agbalagba o
Igba ti mo ro, Ise Iyanu re laye miMo wa ri pe o oga o pupo
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, mo ri pe o gaMo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, more ri pe o gaMo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Ogun ti eniyan ja n’agba, o poju Ogun ewe loTori eni aye ba le, ti aye o ri mu ni ogun to sanra doju koIdi ti aye fin le ni, Oye aye, Olorun mi mo oooOju ogun laye je feni to waye o wa se rereMo wa ronu jinleAanu re lori aye miEmi ri pe o ga o, pupo
Igba ti mi ro anu re lo ri miMori pe oga, mo ri pe o gaMo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro anu re lo ri miMori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, mo ri pe o gaMo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Ose Olorun, Iwo lo je ki ewu aye fo mi daIya to je mi, o je ko je mi gbe o, baba o seun.A pe omo lowo eyinOluso agun fun miOlorun iwo niIwo lo gbe mi ro, eniyan o le seyi o afi iwoO gbe mi so ke gogoro, Osuba re o babaEyi ni mo se isiro fun titi, ogbon ori mi ko gbe
Igba ti mi ro ife nla re Lori miMori pe oga, more ri pe o gaMo ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ife nla re lori miMori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Igba ti mi ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, more ri pe o ga Baba.
Igba ti mo ro ise iyanu re laye mi,Mori pe oga, mori pe oga, mori pe oga pupo.
Olorun to ga owa lokeOlorun to be ninu ayeOkere titi, ogba mimo eniyanOwa lotun wa, owa lo si waAyika wa gbogbo, owa ni beOhun ni olorun, afeti lu KaraLarin alawo dudu o n sise e loEyin re eniyan, mo rin ise reAlawo funfun won teriba funAlayi mo n kon, won beere wipeTani olorun, ta lolorunAyanfe ema da won lo wun peIbi gbogbo lo wa ehOlorun agbayeIbi gbogbo lo wa ehAni ko si ibiti oju olorun ko toIbi gbogbo lo waOlorun nla apejuba, arayerorunIbi gbogbo lo waIbi gbogbo lolorun gbeIbi gbogbo lo waO nbe laye, emi awon woli to toIbi gbogbo lo waOro gbe inu omo eniyan fo muIbi gbogbo lo waOti saju aye de, omo inu aye ati eyin ayeIbi gbogbo lo waIbi gbogbo lo wa olodumareIbi gbogbo lo waO nbe larin awon angeli mimoIbi gbogbo lo waKo si ibiti e pe olorun si ti o wa ohIbi gbogbo lo waIbi gbogbo lo wa baba ohIbi gbogbo lo waOlorun ajanaku, ibi gbogbo lo wa babaIbi gbogbo lo waO nbe lokan re ti o ba gba layeIbi gbogbo lo waIbi gbogbo, ibi gbogbo lo waIbi gbogbo lo wa
DOWNLOAD AUDIO/MP3
ALSO CHECK:   Oh Ye Gates, Let Him In by TY Bello & Tope Alabi

Download Below!

audio Title: Nigbati Mo RoArtist: Tope Alabi

DOWNLOAD MP3

What do you think about this song?

We want to hear from you all.
Drop your comments

ALSO CHECK:   Nathaniel Bassey – There Is A Sound

Upload your Song

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button
Mastodon