Mike Abdul – Iro Ayo Ft. Omotola Jaiyeola
WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
---|

Mike Abdul – Iro Ayo Ft. Omotola Jaiyeola, mp3 Download, Audio, song, music
DOWNLOAD MP3: Mike Abdul – Iro Ayo Ft. Omotola Jaiyeola
Talented Nigeria Gospel Singer and song writer Mike Addu collaborate with Omotola Just
On the Release of the song tagged Iro Ayo
Download Audio song below and drop Your Comments.
Mike Abdul – Iro Ayo Ft. Omotola Jaiyeola
Lyrics
Verse 1
Iro Ayo La o ma gbo nile wa
Sekere ilole ekun
Igbagbo lo so’wa da’segun
Let them know pa’loluwa
Awa oni loju ekun La’ye
Awa oni lereke ose
Ore ofe Oluwa towa
Let them know pa’loluwa
Enu ope wa o’gbolude
Orun si ayo de s’aye
Ayo Olorun s’a lagbara wa
Won ti mo pa’loluwa
Chorus
Iro Ayo eh eh eh eh iro ayo eh
Iro Ayo lawa nfe o iro ayo eh
Iro Ayo ninu ‘le wa
Iro Ayo nirin ajo wa
Iro Ayo lori ise wa
Iro Ayo eh eh
Iro Ayo ninu ‘le mi
Iro Ayo nirin ajo mi
Iro Ayo lori ise mi
Iro Ayo eh eh
Verse 2
Once has He spoken
Twice have I heard
All power belong to GOD
Sing His praise with a shout of joy
Mimo Loluwa Mimo
Gbogbo aye kun fun ogo re Mimo
Awon Orun won wa riri Mimo
Almighty lo’lorunwa
Ayobami Ayomide
Ayomipo Ayomikun
Gbogbo Ayo ni mo kojo sir
Igbala Ayo ti wole de
Chorus
Iro Ayo eh eh eh eh iro ayo eh
Iro Ayo lawa nfe o iro ayo eh
Iro Ayo ninu ‘le wa
Iro Ayo nirin ajo wa
Iro Ayo lori ise wa
Iro Ayo eh eh
Iro Ayo ninu ‘le mi
Iro Ayo nirin ajo mi
Iro Ayo lori ise mi
Iro Ayo eh eh
Vamp
Ayo Ayo Ayo
Ayo Ayo nise
Vamp Adlib
Ayo
Ayo ni mo gbede
Eni ba rimi e gb’ayo
Eni ba gbo mi e gb’ayo
Oun mbase ayo
Ayo ni mo gbede
Gbogbo oun mo dawomile
Lo yori si’re
kiise mimose
Ore Ofe s’a
Ore Ofe s’a o
Eh eh eh eh
Ayo Ayo ni’se
SELAH
DOWNLOAD AUDIO/MP3