🇳🇬 NIGERIA GOSPEL
Kape Laye by Tope Alabi
Follow Us On
WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
---|


Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – Kape Laye.
Multi talented award winning Nigerian Christian Gospel female music minister, music singer, songwriter and worship leader, Tope Alabi has dropped another wonderful brand new gospel music which she titled “Kape Laye”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!
Check Out The Full Lyrics Below!
Kaape laye
Ka lo Ile aye titi Ko ni Kaye gbo ooooooo Aye lole lo niyan keee gbo Igba ta gbe laye Ohun a gbe Ile aye she gbogbo Keledua je kaa le pitan rere Omi aye to ru siwa seyin o Awon kan gbaye Won pitan iṣẹ titi Wọn pitan ìṣòro kolopin rárá Ọrọ wọn o Papa jasayo o’mase O’jojo aye ni won fojú sògbérè ẹkun Titi ikú fi p’awọn won o lenu dupẹ Omi aye to ru siwa seyin ooo Awọn kan gb’ayé wọn jadun ayé Títí won gbàgbé asèdá t’oda ayé Ọrọ’ ayé rú bo wọn lójú jọjọ alumoni Wọn l’ayé wọn f’ogo rẹ fún satani nii Igbagbe ṣewọn pé òun gbogbo tọwọ asèdá wa o’mase o’mase Òun gbogbo toni kaluku ní wọn fi fesu . DOWNLOAD MP3/ AUDIODownload Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments