LYRICSMUSICUncategorized🇳🇬 NIGERIA GOSPEL

Elijah Akintunde – Lodun Yi Ma Ga

Lodun Yi Ma Ga by Elijah Akintunde

Follow Us On
WHATSAPP GROUPTELEGRAM CHANNEL
Elijah Akintunde – Lodun Yi Ma Ga
Elijah Akintunde – Lodun Yi Ma Ga

Elijah Akintunde Lodun Yi Ma Ga Download Mp3 & Lyrics

Nigerian sensational Yoruba gospel artist and award winning songwriter Elijah Akintunde unlocks a captivating new Christian music dubbed Lodun Yi Ma Ga.

This song was released in 2022 and it’s available here at GospelHome alongside it’s lyrics.

Elijah Akintunde Lodun Yi Ma Ga Lyrics

Beat
Lodun yi o n o dide ooo
Maa gaa!!!
Ao fami goke lai fi ti eniyan kan se!!
Owo to n lana fun asegun yoo gbe mi nija
Awada ko oo lodun yi nima rona loo.

Odun to koja
jemi lawon aseyori kan
Beni!!!
Mo sapa sapa sibe ko bo sii funmi
Todun fi yi lo abule ireti ni mowa oo
Nigba to ku kinkin kodun ló mogboju mi soke-
Mo wipe oluwa sodun yi a tun lobeni.
Baba wipe omo fokanbale di e loku
Odun to ma wo yi gangan lodun ayo ree
Eni to seleri sa ti so pe mio ni lélę
Ęfę ko oo lodun yi ni ma rona lòò
Beat
Mo ti n rapęrę pemi lokan tin o tayo
Gbogbo o n to yi mika lo n fo un ire si mi
Mo ti nroye igbega ti koni atako
To bati sęlę eyan mi ko wa bami yo ooo
To ba jęniyan lo so ni mole pe ędę nii
Sugbon olorun fun rare ma lo so funmi
O wipe omo dide kankan tori wo lo kan!!
Mo ti bawon yo lojosi ęho bami yo oo
Oba to ngbeniyan soke so pemi malokan
Awada kó oo lodun yi ni malaluyo…
Gbogbo n ti moti feti gbo pe molaye nibi giga ala ti mo la labule fidorę molę pe mo maa gaa…
Loto abule ni mowa sugbon mo n riran ibigiga. ota sapa tiwon ki iran ayo yi malesę..
Won gbe igi dana kin mabale koja lò
Boluwa se lana Komi ko ye ota mii
Owo to lana komi so pe moma doke
Awada ko oo lodun yi nima rona lo!!!
Beat
Awada ko oo lodun yi moma rona lo ooo
Awada ko oo lodun yi moma rona lo
Ope mo ti n ka calendar lodun yi moma rire gba o!!!!
Awada ko oo lodun yi ni ma rona lo
Ki idiwo kuro lona mi o ki n ribi lo laye ooo
Awada ko oo lodun yi ni ma rona lo
Ko so n toleyę oo odun ayo mi ti de ooo
Awada ko oo lodun yi ni ma rona lo
Ileri igbega ojo wonni osę funmi kanka
Awada ko oo lodun yi ni ma rona lo
Beat
Baba mo n foworę soya 2x
Un o ni jekoro ninu Odun yi oo
Mo fowo olorun soya mi oni lakisa kęhin àsò.
Baba mo n foworę soya 2x
Un o ni jekoro ninu Odun yi oo
Mo fowo olorun soya mi oni lakisa kęhin àsò.

ALSO CHECK:   Amazing God by Sonnie Badu (Music & lyrics)

Emi mimo emi foworę so ya, olori aye mo n foworę soya,mo gbagbo ninu rę mio lęlomiran,iwo lakoni ninu aye mii iwo Lori sun ti mogbekele iwo ni oro to ngbe oro mi Ajide atiye orukore manii,jehovah mo nfowo re soya tori mòmo ó bi akoni eleru
Momo ó bi kiniun juda emi mimo oo Mo nfowore soya mi oni jekoro ninu odun yi oo mo nfowo oluwa soya mio ni lakisa kehin aso.
Baba o baba o baba o owo re mofi soya oo

ALSO CHECK:   Never Lost A Battle by Pastor Ifeoma Eze

Baba mo n foworę soya 2x
Un o ni jekoro ninu Odun yi oo
Mo fowo olorun soya mi oni lakisa kęhin àsò.
Bogun aye ti le to koni bori mi
Biji ti wuko poto ko ni gbemi mii
Ota na owo ika sinu aye mi oluwa ge owo ndanu o so sina,
Ota lero buburu lori aye mi
Oluwa sope ma bori ota mii
Mogbagbo ninu ree mo nfowore soya
Mo mo ise agbara re mo si fowo re soya
Momo agbara to ni mo si fowo re soya
Emi oni je koro ninu odun yi oo2x loruko jesu!!
odun to nlo yi odun ayo mi nii
Dipo ikoro adun ni funmi
Dipo ekun erin ni funmi
Mio ni mobanuje moma rerin ayo amin
Jehovah emi nfowore soya
Mio ni jekoro ninu odun yii o
Mofowo olorun soya mi oo ni lakis kehin aso.
Baba mo nfowore soya 2x
Un o ni jekoro ninu odun yi oo
Mofowo olorun soya mi o ni wo akisa kehin aso.
Mofo olorun soya mi o ni lakisa kehin aso4x

DOWNLOAD AUDIO/MP3

Download Below!

audio Title: Lodun Yi Ma GaArtist: Elijah Akintunde

DOWNLOAD MP3

What do you think about this song?

We want to hear from you all.
Drop your comments

Upload your Song

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button
Mastodon