🇳🇬 NIGERIA GOSPEL

E Gbe Ga by Tope Alabi

Follow Us On
WHATSAPP GROUPTELEGRAM CHANNEL
Tope Alabi – E Gbe Ga
Tope Alabi – E Gbe Ga

Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – E Gbe Ga.

Multi talented award winning Nigerian Gospel female music singer, songwriter, worship leader and music minister, Tope Alabi has released another amazing brand new gospel music which she titled “E Gbe Ga”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!

Check Out The Full Lyrics Below;

E gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooOba to yi gbe aye mi padaEba mi gbe gaOun lo so ekun mi derinEba mi gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooOba to yi gbe aye mi padaEba mi gbe gaOun lo so ekun mi derinEba mi gbe ga ooBi mo ji lowuro, ma gbe gaOwuro mi t’Oluwa niOlugbe ori mi soke niLosan ma yin Oluwa, ma gbe O gaO fun mi lonje oojo o, ki febi pa miToba dale ma yin oTori oun lolusoaguntan miNigba kigba laye kayeMa gbe o gaE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooOba to yi gbe aye mi padaEba mi gbe gaOun lo so ekun mi derinEba mi gbe ga ooMo yin Oluwa oo, mo gbe o gaOba to so mi deni gigaTo gbekun ose lenu miO fibukun ore ko mi lonaO fade wura de mi lo riO gba mi lowo otaGbi gbega Olorun miOre to se laye mi akaikatan, ma gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooOba to yi gbe aye mi padaEba mi gbe gaOun lo so ekun mi derinEba mi gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooE gbe ga, E gbe ga oo, E ba mi gbe ga ooOba to yi gbe aye mi padaEba mi gbe gaOun lo so ekun mi derinEba mi gbe ga ooArabata ribiti OlódùmarèỌlọ́run àwọn ọlọ́runMa gbe ga ma gbé ga o baba o se(Má gbé ga oo)Ìwọ lọ lọrun tí ó lafiweKò sí rú rẹ, láyè lọrunMá gbé ga má gbé ga ó bàbà ó ṣe(Magbe gaa ó)Èmi ó ní sàì gbé ọ gaKò kuta ile, má gba ṣé mi ṣéMá gbé ga má gbé ga ó baba ó se(Má gbé ga ó)Gbígbé ga ní o, ọba tó mọ yẹ irawoMá gbé ga má gbé ga ó bàbà ó ṣeMá gbé ga oỌrẹ elese tó yí lè ayé mi padaTo sọ mí dẹni ọtunMá gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣeMá gbé ga oÌgbà mo ń bẹ láyé má yín ọ óỌlọ́run ayọ’ mi òMá gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣeMá gbé ga oMá yín ó títí Imi mi yóò fi pínA lo ju bẹ ẹ lọọMá gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣeMá gbé ga oỌba tó sọ ẹkùn mi derinÒun ló ní kín máà yooMá gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣeMá gbé ga oMá gbé ga, Magbe ga, Magbe ga,Ọlọ́run ayo mi ooMá gbé ga Magbe ga ó bàbà ó ṣeMá gbé ga oE ó, e o, ẹyin OlúwaE ó, e o, ẹyin OlúwaGbógbó àgbáyé tí tí ayé, tí tí ayéTiti ayé é, má yín OlúwaGigiga nínú, ọlá ńlá Ọlọ’run ỌbaTí tí ayé, má yín OlúwaTiti ayé, títí ayéÒpó mú lérò, ìwọ ni bàbá ẹ ṣéTiti ayé, títí ayéTiti ayé ẹ, má yín OlúwaKabiyesi mo gbósu baOse ó bàbàOba titi aye oo, ose oỌlọ’run pípé ni oA lai labawonOba titi aye oo, ose oKari aye kari olaỌba tó ń bẹ nibi gbogboOba titi aye oo, ose oA rí ro àlá, àdììtú OlódùmarèOba titi aye oo, ose oAlágbára ńlá ń láOmi tí ń mi le ayeOba titi aye oo, ose oA báni já, má je bíA ń ké pe nibi, ọrọ ó ń su wọnOba titi aye oo, ose oÀìkú, aisa, aidibaje, Ọlọ́run ti kí ṣe ènìyànOba titi aye oo, ose oOyigiyigi ọba tí kì sún, Kìí de tó rún gbeOba titi aye oo, ose oÒkúta ìdí gbó lu ni o, Ilé ìṣo agbára miOba titi aye oo, ose oChineke idinma Imela ooOba titi aye oo, ose oAbasi so so o, Abasi amanamoMomiri maku abo o, wame eOba titi aye oo, ose oAlmasiu séríkí ngigi, nagode yesuOba titi aye oo, ose oAsa agbara kiki da agbaraOwo nla arogun má ti di oooOba ńláńlá ńláTo lo kanrin kese to lo kan rinnnnnKeeeeeese


DOWNLOAD AUDIO/MP3

Download Below!

audio Title: E Gbe GaArtist: Tope Alabi

DOWNLOAD MP3

What do you think about this song?

We want to hear from you all.
Drop your comments

Upload your Song

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button
error: