🇳🇬 NIGERIA GOSPEL
Oore Oluwa by Tope Alabi
Follow Us On
WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
---|


Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – Oore Oluwa.
Multi talented award winning Nigerian Christian Gospel music minister, music singer and songwriter, Tope Alabi has released another powerful brand new gospel music which she titled “Oore Oluwa”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!
Check Out The Full Lyrics Below;
E fi’ba fun Un, e yin I o
Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye E fi’ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye K’orin tuntun s’Oluwa iwo okan mi E ma yo n’nu Oluwa eyin olododo Nitori iyin ye fun Oluwa E fi duru yin Oluwa t’ohun t’eelo orin K’orin naa s’oke kikan k’aye ko gbo o Nitori ile aye kun f’aanu Re E fi’ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye Emi t’a dalarr ti a dariji Emi t’Oluwa gba la, t’O se’gun fun Okan mi k’orin yin Oga ogo Awon angeli juba Re lojoojo Agbaagba lorun f’iba yi ite Re ka Pipe lo je ogo, lailakawe E fi’ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye Mo f’eru gbe E ga, mo yin Oga ogo O so ibu omi po, O gba okun jo O s’oro, o si ti se mo yin O, Oluwa E fi’ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti yeDidara ni ike, didara laabo
Didara ni ife, didara laabo O po loore, O po ni’bukun o Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo Didara ni ike, didara laabo Didara ni ife, didara laabo O po loore, O po ni’bukun o Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo Ninu opo ife lo ragabo mi Oore ofe Re ni mo n je Ibukun Re to po, lo je k’emi po Ninu ogo Re lokan mi n yo Ohun gbogbo lO fi se ‘ke mi Oba Onike, didara ni O Didara ni ike, didara laabo Didara ni ife, didara laabo O po loore, O po ni’bukun o Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo O gba mi lowo ogun idile Mariwo mi yo laarin igbago Ogun ibi a ti bi d’atemole Bi t’ota se po to won dake jeje Apenimadani, didara ni O Didara ni ike, didara laabo Didara ni ife, didara laabo O po loore, O po ni’bukun o Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogboAlainironu o ni le dupe
Mi o ni ya ‘baramooreje Olori ogun to f’ife ja ‘ja ikoro lori aye mi mo dupe Ope mi ka sai gun lailopin titi laye Aabo Re ti o ka lori ebi mi, komboki oore Olorun to dara ni’ke, ige, Iwo ni maa sin o Onife alailodiwon, Oloore mi O se Didara ni ike, didara laabo Didara ni ife, didara laabo O po loore, O po ni’bukun o Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo Igba ti ogun dide ija oloro (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Igba ti eni a ro bi ore d’ota gbangba (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Igba eti ore gbo ogun, to f’ese fe (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Igba t’afeniferere o le rerin mo o (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Igba t’ebi wa ninu ipaya ogun oro o (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) T’abanijiroro o le beere eni mo, o ma se (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Olufe owon, Iwo nikan n mo ri o (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Igba ti ile kan roro, ti ito enu gbe lau (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Igba t’adura at’aawe di sisa, aisoje rara (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Igba yi mo wa r’arisa eniyan bi won ti n jehun eni t’on pani (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) As’ologo asun mala lakun nirin ajo aye yi (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Iwo to m’ooto oro, to mo ‘bere to mo ‘bi ti o pin si (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Arinurode Olumoran okan lo yo mi o Ose (Iwo, Iwo, Iwo nikan lo n gbe mi ro) Didara ni ike, didara laabo Didara ni ife, didara laabo O po loore, O po ni’bukun o Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogbo Didara ni ike, didara laabo Didara ni ife, didara laabo O po loore, O po ni’bukun o Mo wa f’iba fun O, Oba t’o n s’ohun gbogbo ninu ohun gbogboDOWNLOAD AUDIO/MP3
Download Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments