LYRICS🇳🇬 NIGERIA GOSPEL

Mr Gbera ft Alaseyori – Iru Eriri

Follow Us On
WHATSAPP GROUPTELEGRAM CHANNEL

Mr Gbera ft Alaseyori – Iru Eriri, mp3 Download, Audio, song, music

DOWNLOAD MP3: Mr Gbera ft Alaseyori – Iru Eriri

DOWNLOAD MP3: Mr Gbera ft Alaseyori – Iru Eriri

Talented Nigeria Gospel Singer Mr Gbera Collaborate with Alaseyori
To Release new Gospel song Tagged Iru Eriri
Download Audio song below and share.

Mr Gbera ft Alaseyori – Iru Eriri

DOWNLOAD MP3

Iru Iriri Lyrics ft Adeyinka Alaseyori

Eyi to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Iru iriri ti mori gba won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

ALSO CHECK:   mercy chinwo chinenye ndu

Ohun gbogbo to jababara fun won
sebohun lofi sara fun wo
Ohun toje ipalara fun won
ara irelofi jasi femi
tori moranugba ni

Ohun to lakoja to fa eri
lofa iku opolopo
oje dupe

Ona to hun lo to nmu onje wale
lomu opo lo orun oje dupe
Ona ofun re oda ona iku
oje dupe
Omo tori gbedani ohun logba emi opolopo oje dupe

ALSO CHECK:   Lawrence Oyor – My Daddy My Daddy Mp3 Download

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

Orisirisi iriri lohun sele
Aimoye nkan ta ogbori losele
Gbogbo orile ede ohun be ni titi

Iru iriri ti mori gba la won kori
Sugbon anu ti morigba woko ri gba

DOWNLOAD AUDIO/MP3

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button
Mastodon