🇳🇬 NIGERIA GOSPEL

Mimo L’Oluwa by Tope Alabi

Follow Us On
WHATSAPP GROUPTELEGRAM CHANNEL
Tope Alabi – Mimo L’Oluwa
Tope Alabi – Mimo L’Oluwa

Another lovely brand new gospel music from Tope Alabi – Mimo L’Oluwa.

Nigerian talented award winning Christian Gospel music minister, music singer and songwriter, Tope Alabi has released another amazing brand new gospel music which she titled “Mimo L’Oluwa”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!

Check Out The Full Lyrics Below;

Mimo LoluwaMimoAngeli won mi keAwon Orun mi keMimoEgbageje irawoMimoMimo LoluwaMimoAngeli won mi keAwon Orun mi keMimoAgbagba merinlelogunLorigun mererin aye oMimoAtoke atileMimoSe ni won nke tantan oMimoTa ni yo gori Oke oluwaMimoTabi tani yo duro nineMimoEni to ni owo Mimo, ati aya funfunMimo o loluwaMimo o Mimo o Mimo oMimo o fun fun nene niMimoKabiyesi eledumare Oba MimoOba NLAGbogbo aye e teriba fun Oba adari hurunOba to ni emi inu eniyan pataOnikokoro aye lowoAdagagodo emi gbogbo eniyanOlukangun orun, ajosun edumareJigbinigbin, awuwo bi ate ilekeMimoOpa tirin kanle o kan orunAjosun edumare, minimini ojo to njara o deyanMimoOrun wawa nigba to padabo sipoOlorun to sosupa dale torutoruOba toun Soun gbogbo lasiko lasikoOba to let feyin eni ti, ta le feyin re ti laelaeAre NLA, Oga tenikan o biTo bimo Kari aye porogodoOlowori gbogbo aye, orogodigo baba awon eruMimo MimoOniwa funfun, oba adake se in,Tenikan o le se un siNinu ogo gangan lo ti fohunOlogo to ju Ogo lo niMimo.Kabiyo o si, emi o je fi osere, afi eni to be fegba query lido re.Mi o je foju di oOba ti o se wo loju woO ti e leti, ai le dibaje ni oBaba NLA Ku Baba miO le pin yikinMimoGbogbo eni to be mi riri Oluwa, e Teri baEwa riri fun Oba tite re ki siIbere at opin, Olorun ajanaku, tin mi gbo kijikijiMimoTabubu, tale bu tan, pupo si ni gbogbo ojoEje ka sale fun Oba rere ta ba mo ririEmi inu awon woliAtobitan, alainiye, popo koja ririTerere koja kika, gungun lailopinAiletuwo, adaun ro, adaun se, adaun soOluwa inu awon orun, Oke NLA, arogunmatidiArabaribiti, aribirabataEjinkota biko yingirinOjo foke bi koyegereOke o le SA, Oke o le heKoseni to le no aditu re, OlodumareIwo Lodi Iwo lo le tu, Oba NLA gbogbo agbaye lounTeriba fun o baba AgbaGbangba gbangba, jaranjaran, fenfefenfeIba o ibaIwọ lodi Iwọ lo lè tu,Ọba nla gbogbo àgbáyé lòún tẹriba fún ọ baba AgbaGbángba gbángba, jaranjaran, fenfefenfeIba o iba…Mímọ L’oluwaMímọAngẹli wọn mi keMímọÀwọn Ọrùn wọn mi keMímọEgbaagbeje ìràwọMímọ

DOWNLOAD AUDIO/MP3
ALSO CHECK:   Chidinma – For You ft. Fiokee

Download Below!

audio Title: Mimo L’OluwaArtist: Tope Alabi

DOWNLOAD MP3

What do you think about this song?

We want to hear from you all.
Drop your comments

ALSO CHECK:   Chukwu Okike by Zimuzor

Upload your Song

Related Articles

Leave a Reply

Back to top button
Mastodon