| WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
|---|
E ti tobi to By EmmaOMG ft The OhEmGee Choir MP3 DOWNLOAD LYRICS
Another brand new Gospel worship song Tagged E Ti Tobi to by EmmaOMG ft The OhEmGee
Multi Talented Nigerian Popular Gospel Singer and worship leader popular know by his stage name EmmaOMG dash out new gospel worship song Tagged E ti Tobi to featuring Talented Nigerian Gospel Minister OhEmGee.
Download MP3 song below and share with your love once 😘.
E Ti Tobi To LYRICS by EmmaOMG
E Ti Tobi to (Live) ft. The OhEmGee Choir, Pelumi Deborah & BBO – EmmaOMG
…
…
Oluwa tobi ni sioni
O si joba lori gbogbo orile ede
Je ki won yin oruko re ti o tobi ti osi leru
Oh my God……
Lead :Gbogbo aye n wariri ni oruko re Won nkorin
Response : Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re o,won so wipe
Response : Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Won ni Eti tobi to o
oh oh oh oluwa
Response : Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Won ni eti tobi to o,
oh oh oh oh oluwa wa o
Response : Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Awon oke nla nla won foribale o Tori iwo ni ogo ati ola ju oke nla ikogun won ni lo o
Response : Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Iwo ti olorun ji dide ninu oku lati gba wa kuro ninu ibinu ti n bo o
Response : Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Iwo oluwa olorun to n gbe larin awon kerubu to po ni ipa ati agbara o
Response : Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin ….yeee
Response : Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re
Response: Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Eti tobi to o
oh oh oh oh oluwa wa o
Response : Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Ipekun ola , Ipekun iye ye eh eh eh eti tobi to oh oh oh oh
Response: Eti tobi oo Jesuuuuu
Lead : Ireti wa o , eri wa o oh oh oh eti tobi to oh oh oh
Response : Eti tobi to ooo Jesuuuuu
Lead : Itan sho to wole ro ro ro ro ro Eti tobi to aye ati orun n bo oo
Response : ( Won n juba ) eti tobi to o Jesuuu ( won foribale)
Lead : Jordani ri o o pada seyin ,okun ri o o sa Eti tobi to olodumare
Response : Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Abetilukarabiajere baba mi agba oye Eti tobi to oh oh oh oh oh
Response: Eti tobi oo Jesuuuuu
Lead : Tori na gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Response : Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re eh eh eh
Response : Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Won ni eti tobi to oo oh oh oh oluwa wa
Response : Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Gbogbo idile Jesse, jesu won nkorin foribale won so wipe
Response : Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Ipekun ola Ipekun Oro , Ipekun agbara oh eti tobi to Eti tobi to oh oh oh oh oh
Response; Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Ore ati ola nla ni o wa ni iwaju re ,ipa ati ewa nbe nibi mimo re
Response: Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Aiikakatan o, aiibubutan o atobi loye ongbe leyin eni a n da loro oo Eti Eti Eti tobi to o
Response: Eti tobi to o Jesuuuuu
Lead : Jesu gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Response Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Awon orun n seleri won foribale niwaju ite re ohhhh eh
Response Eti tobi to oo Jesuuuuu
Lead : Won juba fun ajunilo o, eba n juba f’ajunilo eh ,e ba n seba f’ajunilo o,e ba gbo’suba f’ajunilo ,e ba n gbo osuba f’ajunilo o,e ba n kira f’ajunilo o ,e ba n juba f’ajunilo o,e bami juba f’ajunilo e ba n gbo’suba f’ajunilo o ,e ba n seba f’ajunilo o,
Ani gbogbo aye n wariri ni oruko re won nkorin
Eti tobi to o Jesuuuuuuuuu
Oh My God
DOWNLOAD AUDIO/MP3Download Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments

