🇳🇬 NIGERIA GOSPEL
Adake Dajo by Tope Alabi
Follow Us On
WHATSAPP GROUP | TELEGRAM CHANNEL |
---|
Another lovely brand new gospel song from Tope Alabi – Adake Dajo .
Talented award winning Nigerian Christian Gospel female music singer, songwriter, worship leader and music minister, Tope Alabi has released another amazing brand new gospel music which she titled “Adake Dajo”. And it’s right available here on Gospelhome.com.ng for your free and fast download!
Check Out The Full Lyrics Below;
Adake dajo
On lo mo wa o, O mi wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa o Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koroAdake dajo
On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koroEni to da oju o, ko ni s’alairiran
Olu to da eti o, ko le s’alaigboran Ko si koro loju Re, gbangba kedere lo ri gbogbo waAdake dajo
On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koroK’a ye s’esin, k’a ye pe e ni esin, k’a lo ja’wo pata
A o le gan Olorun pelu ‘gbagbo oju tori ko ni le gba wa A n fi ti’pa gboran si ‘lana esin, ofin Olorun wa d’afieyin Opo dara loju, iwa won o dokan T’egbin t’idoti ko je k’adura opo onigbagbo o gba Ojiji t’Eleda da mo wa, o n s’afihan ohun ikoko o E o ni le gba’bode f’Olorun, onitohun a wule tan ‘ra e pa Olorun alawopa, dakun ma wo mi paAdake dajo
On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koroEemo to wo ‘jo Olorun ti wa bureke, gbogbo aye di ‘ranse Olorun
At’eni Baba ran, at’eni ebi le de Woli osan gangan, iyen lo bi rere Ori pepe di ‘gbale egungun At’alafose at’elepe Ogo ologo de ku t’on mi wo s’agbara Igbadi m be labe collar opo won Awon t’ogun nja t’on tori k’ogun o le se t’on wo ‘nu ijo wa O ma se arakun laso gbagi logun to n kun ogun won Ab’e o ri ijo, ki Jesu to de ki ni yio da oAdake dajo
On lo mo wa o, O n wo wa w’okan Ohun gbogbo ti a gb’aye se On lo da ojiji mo wa Ipilese aye wa ooo, at’opin re, O ri gbogbo koroE je k’a bi ‘ra wa leere, gbogbo iranse Olorun pata
Kini idahun si ibeere yi o Oro ijoba orun ti di ‘waasu igbaani lenu wa Ere wo lonisowo agba n je ninu ise wa E gbo ere wo, ere wo, lOluwa n je A fowoleran O ma n wo wa o Ko ma ka ‘se mi lai lere kankan Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so T’a ba p’oruko ni’joba orun T’a pe won titi ti o de kan e o Eni to n toka s’omo apaadi, at’eyin to mo ‘mo ile ologo T’on ba p’oruko ni’joba orun, t’on o ka mr census e ki loo ro Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Onigbagbo ka ri mi ete eke Lati inu ijo je ‘ra wa lese dede Adura at’aawe odi s’enikeji Ife ikoko lori pepe si pepe E o ranti O da ogbon o ju ogbon lo E o ba lako bi ibon lese-o-gbeji Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Ojo nla, Adajo aye fere de Aiyiwapada idajo a ro K’onikaluku lo ye ‘ra e wo Ibi t’o ba ku si, gb’adura k’o tun se Ko ma ba di ki loo ro K’enu ma wo ji, ailesoro Ki loo ro, ki loo so Nigba t’a ba p’oruko awon eniyan Ta o ba pe omo omo o Ki loo ro, ki loo so Eh eh eh eh eh eh mo wi t’emi o, ore ma di’ti Ko ma di’na orun mo ‘ra e, o ti n f’ami han, Jesu o ni pe de Eru igi to n be loju re, lo gbe kuro, ko ye tenubole soroLo ronu ko pa iwa da, ka si toro fun aanu
K’a ju’wo ju’se k’a tuba f’Olorun, K’a le ba joba, k: a le ka wa mo won Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s’asaro aye re Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s’asaro aye re Ise wa laye yi ni lati wa ijoba Olorun Leyin re, ohun to ku, a o fi fun wa O n bo laipe, s’asaro aye reDOWNLOAD AUDIO/MP3
Download Below!
What do you think about this song?
We want to hear from you all.
Drop your comments